Èyin Nìkan lyrics

by

Congress MusicFactory


ÈYIN NÌKAN

[ẹsẹ]
Pelu gbogbo okan mi ni mo juba re
Ni gbogbo aye mi ni mo b’owo fun
Olu aye mi, ni mo fun l’oun gbogbo
Mo fi iyin fun eyin nikan

[ẹsẹ]
Pelu gbogbo okan mi ni mo juba re
Ni gbogbo aye mi ni mo b’owo fun
Olu aye mi, ni mo fun l’oun gbogbo
Mo fi iyin fun eyin nikan

[Akorin]
F’eyin nikan, eyin nikan
Mo fi iyin fun eyin nikan
Eyin nikan, eyin nikan
Mo fi iyin fun eyin nikan

[ẹsẹ]
Pelu gbogbo okan mi ni mo juba re
Ni gbogbo aye mi ni mo b’owo fun
Olu aye mi, ni mo fun l’oun gbogbo
Mo fi iyin fun eyin nikan

[Akorin]
F’eyin nikan, eyin nikan
Mo fi iyin fun eyin nikan
Eyin nikan, eyin nikan
Mo fi iyin fun eyin nikan

[Akorin]
F’eyin nikan, eyin nikan
Mo fi iyin fun eyin nikan
Eyin nikan, eyin nikan
Mo fi iyin fun eyin nikan

[ipari]
Mo fi iyin fun eyin nikan
Mo fi iyin fun eyin nikan

A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z #
Copyright © 2012 - 2021 BeeLyrics.Net