Olórun wà níhîn (Halleluya) lyrics

by

Congress MusicFactory


OLÓRUN WÁ NIHÍN (HALLELUYA)

[Akorin]
Halleluya!
Halleluya!
Halleluya!
Oluwa Olorun wa nihin

[Akorin]
Halleluya!
Halleluya!
Halleluya!
Oluwa Olorun wa nihin

[ẹsẹ 1]
E wa laarin eniyan yin
Ogo Re si nbuyo
Fihan kakiri agbaye
Ninu olanla Re joba

[Akorin]
Halleluya!
Halleluya!
Halleluya!
Oluwa Olorun wa nihin

[Akorin]
Halleluya!
Halleluya!
Halleluya!
Oluwa Olorun wa nihin

[ẹsẹ 2]
Pawa mo ka di mimo
Mu wa rin gbogbo ona
Dari wa s’ayeraye
Titi lailai ao ma wi

[Akorin]
Halleluya!
Halleluya!
Halleluya!
Oluwa Olorun wa nihin

[Akorin ipari]
Halleluya!
Halleluya!
Halleluya!
Oluwa Olorun
Oluwa Olorun
Oluwa Olorun wa nihin

A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z #
Copyright © 2012 - 2021 BeeLyrics.Net