Soke lyrics
by Sarz
[Intro]
Eh-eh
By, Sarz, Sarz, Sarz, Sarz, eh
[Verse 1]
Karo oji re, Nini dé
Orí mi wá'rẹ, Nini dé
Boy mí ti jẹ lotto-to, l'òní, ah
Boy mí ní ká bo dé l'odò, eh
[Chorus]
In the time of ìjọ Shina, I was the dancing genius, te lè mi to the dance floor, je ká jọ ṣeré
In the time of ìjọ Shina, I was the dancing genius, te lè mi to the dance floor
[Bridge]
Gbèsè kàn sókè, sókè
Gbèsè kàn sókè
[Chorus]
Mó rí ìjọ yẹn, mó rí ìjọ yẹn, eh-eh
Mó rí brother yẹn, mó rí sister yẹn
Mó rí ìjọ yẹn
Má sọ mi di àpẹẹrẹ, àpẹẹrẹ Ajase (Mó rí ìjọ yẹn)
Àwọn girls ọ gbá gbere, àpẹẹrẹ Ajase (Mó rí ìjọ yẹn)

Àwọn girls ọ gbá gbere, gb'ọwọ dé o ma dúpẹ (Mó rí ìjọ yẹn)
Ẹni, eji, eta, ayo, ayo, ayo, ayo, ah
[Verse 2]
Lalala-lala, la-lala
Lalala-lala, la-lala
Má sọ mi di àpẹẹrẹ, àpẹẹrẹ Ajase (Lalala-lala, la-lala)
Àwọn girls ọ gbá gbere, gb'ọwọ dé o ma dúpẹ (Lalala-lala, la-lala)
Ọya gbé sókè, ah, gbé sì lè (Lalala-lala, la-lala)
Ọya run mọlẹ, gbé sókè (Lalala-lala, la-lala)
Oya gbé se gbẹ, gbé sì lè (Lalala-lala)
Ọya run mọlẹ (Lalala-lala)
Oya ṣa, ṣ'oye gbé sókè, gbé sì lé, gbé se gbe, gbé sókè (La-lala)
[Verse 3]
Fà mí mọra, talk to me boy
I surrender, 'cause you give me joy
You are my news, I adore you
This is good news, I'll give you joy
[Chorus]
In the time of ìjọ Shina, I was the dancing genius, te lè mi to the dance floor, je ká jọ ṣeré
In the time of ìjọ Shina, I was the dancing genius, te lè mi to the dance floor
[Bridge]
Gbèsè kàn sókè
Gbèsè kàn sókè
[Chorus]
Mó rí ìjọ yẹn, mó rí ìjọ yẹn, eh-eh
Mó rí brother yẹn, mó rí sister yẹn
Mó rí ìjọ yẹn
Má sọ mi di àpẹẹrẹ, àpẹẹrẹ Ajase (Mó rí ìjọ yẹn)
Àwọn girls ọ gbá gbere, àpẹẹrẹ Ajase (Mó rí ìjọ yẹn)
Má sọ mi di àpẹẹrẹ, àpẹẹrẹ Ajase (Mó rí ìjọ yẹn)
Àwọn girls ọ gbá gbere, gb'ọwọ dé o ma dúpẹ (Mó rí ìjọ yẹn)
Ẹni, eji, eta, ayo, ayo, ayo, ayo, ah!
[Outro]
Lalala-lala, la-lala
Lalala-lala, la-lala
Má sọ mi di àpẹẹrẹ, àpẹẹrẹ Ajase (Lalala-lala, la-lala)
Àwọn girls ọ gbá gbere, gb'ọwọ dé o ma dúpẹ (Lalala-lala, la-lala)
Ọya gbé sókè, ah, gbé sì lè (Lalala-lala, la-lala)
Ọya run mọlẹ, gbé sókè (Lalala-lala, la-lala)
Oya gbé se gbẹ, gbé sì lè (Lalala-lala, la-lala)