Eleduwa lyrics
by Barry Jhay
[Intro]
(Mur-Mur-Murderer)
Ijọ buruku lo n'ijọ tuntun
Baba, ṣo n gbọ oun aiyé n sọ?
[Verse 1]
Eleduwa, ẹyin l’akọkọ ninu gbogbo nkan
Kẹ to d'aiye at'ọrun
And that why me I put you first, in everything I do
O ma ma ṣe, Ọlọrun mi, o pọ, o pọ ọ
[Pre-Chorus]
Ibi t’ọn ni ki gbegbe ma gbe lo fi ṣe apartey
Ibi t'ọn ni ki tẹtẹ ma tẹ lo lọ ṣe vaca'
Ngba t'ọn tun wa sọrọ, wọn ni mi mọ ju Ọlọrun lọ
Baba, ṣo n gbọ oun aiye n sọ?
[Chorus]
Ayun lọ, ayun bọ l'ọmọ ẹyẹ n rin
Nkan o ni tabala mi l'ẹsẹ lọla Ọlọrun
L'atoni lọ, k'ọna mi ko la peregede
L’atoni lọ, ma gbe ori’lẹ yi ṣe oun rere
[Verse 2]
Ẹyin to laiye ẹ gb'ohun mi ṣ’aṣẹ pa
I be ọmọ aiye, ẹ duro ti mi, ki n ma ṣe jabọ o
Ikoko la fi ṣe, e gbọdọ fọ o
K'aiye ma fọ igba ikoko mi l'ẹnu
Ay, ti n ba lu n ṣe ni ko ma dun
[Pre-Chorus]
Ibi t'ọn ni ki gbegbe ma gbe lo fi ṣe apartey
Ibi t’ọn ni ki tẹtẹ ma tẹ lo lọ ṣe vaca'
Ngba t'ọn tun wa sọrọ, wọn ni mi mọ ju Ọlọrun lọ
Baba, ṣo n gbọ oun aiye n sọ?
[Chorus]
Ayun lọ, ayun bọ l'ọmọ ẹyẹ n rin
Nkan o ni tabala mi l'ẹsẹ lọla Ọlọrun
L'atoni lọ, k'ọna mi ko la peregede
L'atoni lọ, ma gbe or'ilẹ yii ṣe oun rere
[Outro]
L'atoni lọ, k'ọna mi ko la peregede
L'atoni lọ, ma gbe orilẹ yii ṣe oun rere