Òkùnkùn lyrics

by

Brymo


Hun O farapamo fun e olo mi
E se t'oro re sa fun mi
Hun O s'olugbala
Oto lodun mo wari o
K'owo ore mi le komi yo lododo
Ife nikan loku funmi
Kosenikan to le komi yo

Ajo laye
Hun o mobi mo sewa o
Mo fura pe ibe ni mo nlo
Okunkun lati wa
Okunkun la n lo
A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z #
Copyright © 2012 - 2021 BeeLyrics.Net