Oré lyrics
by Aṣa
[Verse 1]
Ma ya ilé mi, ìwọ orè at'oju b'onilé
Ma ya ilé mi, ìwọ orè agb'oko-l'oko
Ma ya ilé mi, awon orè àdúgbò
Ma ya ilé mi, ma ya lé k'ọmọ
Orè ti mo mu bi àbúrò
Orè, orè ti mo sé dara-dara
Orè ti mo fi nu han
O wa daami loro, o tu mi sita
[Refrain]
Aah, o dab'oro ano
Ei, b'oro ano
[Verse 2]
Don't come to my house, iwo orè éké àdúgbò
Don't come to my house, iwo orè adaléru
Ma ya ilé mi, orè kofeniferé
Ma ya ilé mi o, ma ya lé rárá
Isè ni mo ran wa l'ojo yi o
Oko t'o fèmi s'ilè, ko ku lo wa ìṣe se
L'awon mejéji, won béèrè isé-kuṣé
Wọn wu'wa omodé, wọn ṣé bo ṣe wun wọn
[Refrain]
Aah, o dab'oro ano
Ei, b'oro ano
[Instrumental]
Ei, o dab'oro àná
Aah, b'oro àná
[Verse 3]
E wa wo ija l'ojó yen
E wa wo èrò t'o tu ta
E wa wo eje n'ile
Ah ọrẹ, ọrẹ o, o tú mi s'íta (Ija, ija, ija ma de ile mi)
Má ya ile mi oo, I don't want to see you no more (Ale, ale, ale ma ya ile mi)
Má ya ile mi oo, ti e ma bere mi n'ile (Ija, ija, ija ma de ile mi)
Ah, má ya le mi oo, I don't want to see you no more (Ale, ale, ale ma ya ile mi)
Ọrẹ , iṣé-kuṣe kun owo ọrẹ o (Ija, ija, ija ma de ile mi)
Èmi o ti e le pa ẹ̀yán