Awé lyrics
by Aṣa
[Intro]
Hmmm
[Verse 1]
Awẹ, ibo lo ló ka?
T'a n fi wa o ka
Ibi o ba lo j'a mo
Aunty t'o n gbe'le itosi
O wa o wa'le, yi
Ati o jo meta adabo
O wípé o, o l'oyún fun o
Oyún oṣu meji, o l'oyún fun o
Ani wípé o, o l'oyún fun o
Ìwọ, ìwọ náà
[Chorus]
Wahidi, ọmọ sekina
Ọmọ muyina, ọmọ Mohammed
Wahidi, ọmọ sekina
Ọmọ muyina, ọmọ Mohammed
[Verse 2]
Aynty to l'oyún fun o, o to bi e l'ọmọ
Ìwọ, ìwọ náà
Aunty to l'oyún fun o, ani o to bi o l'ọmọ
Ìwọ, ìwọ náà
O bi'mo oh, oh
O bi'mo
O bi'mo oh, oh
Ọmọ so l'ayo
Ire lo mu ese, irun ori
Iwo dudu, ọmọ pupa
Bawo lo ṣe ri?
[Chorus]
Wahidi, ọmọ sekina
Ọmọ muyina, ọmọ Mohammed
Wahidi, ọmọ sekina
Ọmọ Muyina, ọmọ Mohammed
[Interlude]
Aaaah, aaah
Ewa wo ja l'áàfin oba Ejigbo, ah
At'abo, at'ako
Wọn ja l'áàfin oba, l'áàfin oba o
[Verse 2]
Wahidi, ọmọ Muyina ni, ọmọ sekina
O f'oju mi ri mabo
Mabo n'ile, mabo l'oko, mabo l'Eko
Mama to bi mama re, ni mama mi
Emi náà bi t'emi, bi t'emi
Mo n t'ọmọ l'owo, f'ọmọ l'oyon
Ma ko tire bami
Abo ọ̀rọ̀ la n so f'ọmọluabi
T'o ba de inu re, a d'odindi
Din din