Hey Jago lyrics
by Poco Lee
[Intro: Poco Lee]
Hey Jago! Hey Jago!
Hey Jago! (Ki-) Hey Jago!
[Verse 1: Shoday & Poco Lee]
You dey press money before (That's right)
That one na old taker (Okay)
Me sef go press for sure (You be what?)
I be the new taker (Shoday, kí lo dé?)
Wọ́n ti gbezome (Jẹ́ ó mọ̀)
Old taker ti gbezome (Wahala)
Má lọ́ gbezome
Ọmọ aunty mi no gbezome (Fún wọ́n)
[Chorus: Shoday & Poco Lee]
Hey Jago (Brohz the 'flextion)
What's popping, Jago? (Biggest)
High fashion Jago
Figo ó máà kì n ṣe wazo o (They know)
Hey Jago (Jago)
Èmi ni èèyàn Jago (One-on-one)
Shoday èèyàn Paso (Eish)
Lambo ó máà kì n ṣe wazo o
[Verse 2: Poco Lee]
Hey Jago (Number one)
Gbogbò aṣọ ló ní bàtà (Thеy know)
CEO, high fashion tiwa (Dollar)
Ọmọ Tiamiyu gan-gan (Jẹ́ wọn mọ̀)
Wọ́n dá mọ̀ l'Ókè-Kòtò (International)
Atóóbájẹ́ wọ Morikaz (Jago)
Ojú-Ìrìn, Pen Cinema (Dеy go)
Aja one, aja two (You say what?)
Gbé wọ́n sáré wọ Switzerland (Sherish)
Wọ́n dá mọ̀ l'America (Pe-lorish)
High fashion wọ Canada (Sharp)
Ó y'ẹ́ruku, Jago is loud (Yebo)
[Verse 3: Shoday & Poco Lee]
Tí n bá rí 50 dollar, máa gánu síbẹ̀
No money is ever enough (At all)
Ta, ta ,ta bí Dangote (Shoday)
K'ówó mi kún sókè
I left home to feed home
Mo jáde tán, wọ́n se jollof (Badder)
Go hard or go home (Ekpo)
Ọmọ ìyá mi, má sa lo'le (Yo X)
[Chorus: Shoday & Poco Lee]
Hey Jago (Hey Ja—)
What's popping, Jago? (I don't know)
High fashion Jago (Sheesh)
Figo ó máà kì í ṣe wazo o (Number one)
Hey Jago (Zero, k'ówó pọ̀)
Èmi ni èèyàn Jago (Wọ́n dá mọ̀)
Shoday èèyàn Paso
Lambo ó máà kì í ṣe wazo o (Hey Jago)
[Verse 4: Poco Lee]
Hey Jago (Sheesh)
Gbogbò aṣọ ló ní bàtà (As-in Elder)
CEO, high fashion tiwa (Jẹ́ ó mọ̀)
Ọmọ Tiamiyu gan-gan (You don dey)
Wọ́n dá mọ̀ l'Ókè-Kòtò (You don dey, you don dey, na go jo)
Atóóbájẹ́ wọ Morikaz (You don dey [?] joor, hello)
High fashion wọ Canada (Hey Jago)
Ó y'ẹ́ruku, Jago is loud (Hey Jago)
[Outro: Poco Lee]
Hey Jago! (Sheesh)
Jago, Jago, Jago
Ọmọ líle lápá Agege, wọ́n dá mọ̀ (Yo X)
Yebo
(Ki-)
(Hey Jago, hi—, hi—)