Intro (2024) lyrics
by Tml Vibez
Intro
(Wọn wa mi)
(Wọn wa mi)
(Wọn wa mi)
Wọn wa mi gan-an ni, hm-mm
(Wọn wa mi) ani, wọn wa mi
Verse
From Ipaja mo ti wa Americana
Any currency I go wire
Ah, Tml o ki n wa′ja, ah-ah
Ọmọlọmọ, ọmọlọmọ, ṣanko bọbọ
Ọmọ t'ọn sọ, ọmọ t′ọn sọ, pa wọn bọbọ
Hook
(Wọn wa mi)
America, wọn wa mi
(Wọn wa mi)
Wọn wa mi gan-an
(Wọn wa mi)
Cyprus wọn mi
Hook
(Wọn wa mi)
Ọmọ pupa o n wa mi
(Wọn wa mi)
Ọmọ dudu n wa mi
(Wọn wa mi)
Hook
(Wọn wa mi)
(Wọn wa mi)
Verse
Everything wey we do now money dey involve, emi ọmọ ọgbọn
Them tryna pull me down, lai-lai, ko jọ, ko s'ọmọ na
24-7, hm, eyes on the bag, emi ọmọ Ọlọrun
Money shack pass alcohol