Testimony lyrics

by

BhadBoi OML


Intro
(M-M-Muderer)
Them cover thier head, carry AK twen
I don′t know the thing you una dey call am AK25, (AK47) yes
Them say make we no talk
I say na lie my daddy G.O say I will talk

Intro
Correct, I will talk, I am a chosen
I am a chosen (I am a chosen)
I am a chosen you wicked man who are you? (I am a cho-cho)
Verse
Ayy, ẹni tọ'lọrun pé, ohun lọ′lọrun yàn
Ko to di wo-wo-wo (kò to di wo-wo-wo)
Ọmọ Ọlọhun ń gbọ'
Ọlọhun ń gbọ' ó (Ọlọhun ń gbọ′ ó)
Ọmọ Ọlọhun ń gbọ′ (ọmọ Ọlọhun ń gbọ')

Chorus
I wan give testimo-o, I get one testimony
I wan give testimo-o, I get one testimony
Mo wá dupẹ to ko mi yọ
Otún jẹ k′okó mi yọ, hmm-hmm osé
Yee, Bilikisu má do mí lọ, pa-pa-pa, supe daada
Èlò ni mo gbà ti má gbé raga
Chorus
I wan give testimo-o, I get one testimony
(Èlò ni mo gbà ti má gbé raga)
I wan give testimo-o, I get one testimony
(Èlò ni mo gbà ti má gbé raga)

Hook
Ehh, èmi ó sakọ mọ ohh (uh fafa lé wọn)
Emi ó sakọ mọ ohh (uh fafa lé wọn)

Verse
Normally na wake an bake up
Call my dealer, e never wake up
Mo si crusher mo ri gbẹ ẹsin
Miracle working Jesus
Genesis touch my heart
Exoduxe burst my brain ohh
After this one (after this one)
E mi o mu igbó mọ ó (e mi o mu igbó mọ ó)

Chorus
I wan give testimo-o, I get one testimony
Mo wá dupẹ to ko mi yọ
Otún jẹ k'okó mi yọ, hmm-hmm osé
Yea, Bilikisu má do mí lọ, pa-pa-pa, supe daada
Èlò ni mo gbà ti má gbé raga
Chorus
I wan give testimo-o, I get one testimony
(Èlò ni mo gbà ti má gbé raga)
I wan give testimo-o, I get one testimony
(Èlò ni mo gbà ti má gbé raga)

Hook
Ehh, emi ó sakọ mọ ohh (uh fafa lé wọn)
Emi ó sakọ mọ ohh (uh fafa lé wọn)
Ehh, emi ó sakọ mọ ohh (uh fafa lé wọn)
Emi ó sakọ mọ ohh (uh fafa lé wọn)
Ehh, emi ó sakọ mọ ohh (uh fafa lé wọn)
Emi ó sakọ mọ ohh (uh fafa lé wọn)

Outro
(I am a chosen)
Who mix this (Murderer)
A B C D E F G H I J K L M N O P Q R S T U V W X Y Z #
Copyright © 2012 - 2021 BeeLyrics.Net